Nọ́ḿbà 18:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí o sì mú àwọn ènìyàn rẹ ará Léfì láti ẹ̀yà ìran rẹ láti dàpọ̀ mọ́ ìwọ láti ràn ọ́ lọ́wọ́ nígbà tí ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ ọkùnrin bá ń ṣe iṣẹ́ ìránṣẹ́ níwájú Àgọ́ Ẹ̀rí.

Nọ́ḿbà 18

Nọ́ḿbà 18:1-10