Nọ́ḿbà 18:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mo fún ọ ní gbogbo òróró tí ó dára jùlọ àti gbogbo ọtí titun dáradára jùlọ àti ọkà tí wọ́n mú wá fún Olúwa ní àkọ́so ohun ọ̀gbìn wọn tí wọ́n kórè.

Nọ́ḿbà 18

Nọ́ḿbà 18:10-19