Nọ́ḿbà 16:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Árónì padà tọ Mósè lọ ní ẹnu ọ̀nà Àgọ́ Ìpade nítorí pé àjàkálẹ̀-àrùn náà ti dúró.

Nọ́ḿbà 16

Nọ́ḿbà 16:45-50