Nọ́ḿbà 16:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Iná sì jáde láti ọ̀dọ̀ Olúwa ó sì run àádọ́tàlénígba ọkùnrin (250) tí wọ́n mú tùràrí wá.

Nọ́ḿbà 16

Nọ́ḿbà 16:26-41