Nọ́ḿbà 16:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kórà ọmọ Íṣárì, ọmọ Kóhátì, ọmọ Léfì àwọn ọmọ Rúbẹ́nì: Dátanì àti Ábírámù, àwọn ọmọ Élíábù, àti Ónù ọmọ Pélétì mú ènìyàn mọ́ra.

Nọ́ḿbà 16

Nọ́ḿbà 16:1-2