Nọ́ḿbà 15:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Fún àgbò kan ni kí ẹ pèsè ọrẹ ohun jíjẹ ìdá méjì nínú mẹ́wàá òṣùwọ̀n ìyẹ̀fun kíkúnná tí a fi ìdá kan nínú mẹ́ta òṣùwọ̀n òróró pò.

Nọ́ḿbà 15

Nọ́ḿbà 15:3-10