Nọ́ḿbà 15:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ó dárí ji gbogbo ìjọ ènìyàn Ísírẹ́lì àti àwọn àlejò tí ń gbé ní àárin wọn nítorí pé ní àìròtẹ́lẹ̀ ni wọ́n sẹ ẹ̀ṣẹ̀ náà.

Nọ́ḿbà 15

Nọ́ḿbà 15:21-28