Nọ́ḿbà 15:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni gbogbo òfin tí Olúwa fún yín láti ẹnu Mósè láti ọjọ́ tí Olúwa ti fún yín àti títí dé ìran tó ń bọ̀.

Nọ́ḿbà 15

Nọ́ḿbà 15:18-29