Nọ́ḿbà 15:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ mú àkàrà wá nínú àkọ́so oúnjẹ yín wá gẹ́gẹ́ bí ọrẹ ìgbésókè sí Olúwa, ọrẹ láti inú ilẹ̀ ìpakà yín.

Nọ́ḿbà 15

Nọ́ḿbà 15:14-21