Nọ́ḿbà 15:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ẹ sì jẹ oúnjẹ ilẹ̀ náà, ẹ mú nínú rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọrẹ ìgbésókè wá fún Olúwa.

Nọ́ḿbà 15

Nọ́ḿbà 15:13-27