Nọ́ḿbà 15:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó tún mú ìdajì òsùwọ̀n wáìnì wá fún ọrẹ ohun mímu. Yóò jẹ́ ọrẹ àfinásun, àní òórùn dídùn sí Olúwa.

Nọ́ḿbà 15

Nọ́ḿbà 15:8-12