Nọ́ḿbà 14:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó kọlù wọ́n pẹ̀lú àjàkálẹ̀-àrùn, èmi ó gba ogún wọn lọ́wọ́ wọn, èmi ó sì pa wọ́n run ṣùgbọ́n èmi ó sọ ọ́ di orílẹ̀ èdè ńlá tó sì lágbára jù wọ́n lọ.”

Nọ́ḿbà 14

Nọ́ḿbà 14:2-13