Nọ́ḿbà 13:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì tún rí àwọn òmìrán (irú àwọn ọmọ Ánákì) àwa sì rí bí i kòkòrò tata ní ojú ara wa, bẹ́ẹ̀ ni àwa náà sì rí ní ojú wọn.”

Nọ́ḿbà 13

Nọ́ḿbà 13:28-33