Nọ́ḿbà 13:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì rán wọn jáde láti Aginjù Páránì gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Olúwa. Gbogbo wọn jẹ́ olórí àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì.

Nọ́ḿbà 13

Nọ́ḿbà 13:1-11