Nọ́ḿbà 13:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n padà wá bá Mósè àti Árónì àti gbogbo àwọn ọmọ Ísiréli ní ijù Kádésí Páránì. Wọ́n mú ìròyìn wá fún wọn àti fún gbogbo ìjọ ènìyàn, wọ́n fi èso ilẹ̀ náà hàn wọ́n.

Nọ́ḿbà 13

Nọ́ḿbà 13:17-27