Nọ́ḿbà 13:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ wò ó bí ilẹ̀ náà ti rí, bóyá àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà jẹ́ alágbára tàbí aláìlágbára, bóyá wọ́n pọ̀ tàbí wọn kéré.

Nọ́ḿbà 13

Nọ́ḿbà 13:15-25