Nọ́ḿbà 12:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́ẹ̀kan náà ni Olúwa sọ fún Mósè, Árónì àti Míríámù pé, “Ẹ̀yin mẹ́tẹ̀ẹ̀ta, jáde wá sínú àgọ́ ìpàdé.” Àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta sì jáde síta.

Nọ́ḿbà 12

Nọ́ḿbà 12:1-8