Nọ́ḿbà 11:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní gbogbo ọjọ́ náà àti òru, títí dé ọjọ́ kejì ni àwọn ènìyàn fi ń kó àparò yìí: Ẹni tó kó kéré jù lọ kó ìwọ̀n hómérì mẹ́wáà, wọ́n sì sà wọ́n sílẹ̀ fún ara wọn yí gbogbo ibùdó.

Nọ́ḿbà 11

Nọ́ḿbà 11:22-35