Nọ́ḿbà 11:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì wí fún un pé, “Àbí ìwọ ń jowú nítorí mi? Ìbá ti wù mí tó, kí gbogbo àwọn ènìyàn Olúwa jẹ́ wòlíì, kí Olúwa si fi Ẹ̀mí rẹ̀ sí wọn lára!”

Nọ́ḿbà 11

Nọ́ḿbà 11:28-32