Nọ́ḿbà 11:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì jáde, ó sọ ohun tí Olúwa wí fún àwọn ènìyàn. Ó mú àwọn àádọ́rin (70) àgbààgbà Ísírẹ́lì dúró yí àgọ́ ká.

Nọ́ḿbà 11

Nọ́ḿbà 11:17-31