Nọ́ḿbà 11:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbo ni n ó ti rí ẹran fún àwọn ènìyàn wọ̀nyí? Nítorí wọ́n ń sunkún sí mi pé, ‘Fún wa lẹ́ran jẹ́!’

Nọ́ḿbà 11

Nọ́ḿbà 11:11-21