Nọ́ḿbà 10:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lákòótan, àwọn ọmọ ogun tó ń mójútó ẹ̀yìn ló tún kàn, àwọn ni ìpín ti ibùdó Dánì lábẹ́ ọ̀págun wọn. Áhíésérì ọmọ Ámíṣádárì ni ọ̀gágun wọn.

Nọ́ḿbà 10

Nọ́ḿbà 10:16-27