Nọ́ḿbà 1:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Iye àwọn tí a kà nínú ẹ̀yà Náfítalì jẹ́ ẹgbàá mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n-ó-lé-egbéje (53,400).

Nọ́ḿbà 1

Nọ́ḿbà 1:34-49