Nọ́ḿbà 1:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ìran Bẹ́ńjámínì:Gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ogún ọdún sókè ni wọ́n to orúkọ wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ẹbí àti ìdílé wọn.

Nọ́ḿbà 1

Nọ́ḿbà 1:35-41