Nọ́ḿbà 1:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti inú àwọn ọmọ Jóṣẹ́fù:Láti ìran Éfúráímù:Gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọ́n jẹ́ ogún ọdún sókè tí wọ́n lè lọ sójú ogun ni wọ́n to orúkọ wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ẹbí àti ìdílé wọn.

Nọ́ḿbà 1

Nọ́ḿbà 1:28-39