Nọ́ḿbà 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ àti Árónì ni kí ẹ kà gbogbo ọmọkùnrin Ísírẹ́lì gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn láti ọmọ ogún ọdún sókè, àwọn tí ó tó lọ sójú ogun.

Nọ́ḿbà 1

Nọ́ḿbà 1:1-12