Nọ́ḿbà 1:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ìran Júdà:Gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ogún ọdún sókè, tí wọ́n le lọ sójú ogun ni wọ́n to orúkọ wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ẹbí àti ìdílé wọn.

Nọ́ḿbà 1

Nọ́ḿbà 1:24-34