Nọ́ḿbà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ka gbogbo àgbájọ ènìyàn Ísírẹ́lì nípa ẹbí wọn, àti nípa ìdílé baba wọn, to orúkọ wọn olúkúlùkù ọkùnrin ní ọ̀kọ̀ọ̀kan.

Nọ́ḿbà 1

Nọ́ḿbà 1:1-8