Nọ́ḿbà 1:10-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Láti ọ̀dọ̀ àwọn sọmọ Jósẹ́fù:láti ọ̀dọ̀ Éfraimù, Elisámà ọmọ Ámíhúdì;Láti ọ̀dọ̀ Mánásè, Gámáélì ọmọ Pedasúrù;

11. Láti ọ̀dọ̀ Bẹ́ńjámínì, Ábídánì ọmọ Gídíónì;

12. Láti ọ̀dọ̀ Dánì, Áhíésérì ọmọ Ámísádáì;

13. Láti ọ̀dọ̀ Áṣérì, Págíélì ọmọ Ókíránì;

Nọ́ḿbà 1