Nehemáyà 7:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo fún Hánánì arákùnrin mi pẹ̀lú Hananáyà olórí ilé ìṣọ́ ní àṣẹ lórí Jérúsálẹ́mù, nítorí tí ó jẹ́ ènìyàn olóòótọ́, ó sì bẹ̀rù Ọlọ́run jù bí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ti ṣe lọ.

Nehemáyà 7

Nehemáyà 7:1-70