Nehemáyà 6:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ṣíwájú sí í, wọ́n túnbọ̀ ń ròyìn iṣẹ́ rere rẹ̀ fún mi, wọ́n sì ń sọ ohun tí mo sọ fún-un. Tòbáyà sì ń kọ àwọn lẹ́tà ránṣẹ́ sí mi láti dẹ́rù bà mí.

Nehemáyà 6

Nehemáyà 6:12-19