Nehemáyà 4:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe bo ẹ̀bi wọn tàbí wẹ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wọn nù kúrò níwájúú rẹ, nítorí wọ́n mú ọ bínú níwájú àwọn ọ̀mọ̀lé.

Nehemáyà 4

Nehemáyà 4:2-13