Nehemáyà 4:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ọjọ́ náà lọ, ìdajì àwọn ènìyàn ń ṣe iṣẹ́ náà, nígbà tí àwọn ìdajì tó kù múra pẹ̀lú ọ̀kọ̀, àṣà, ọrun àti ìhámọ́ra. Àwọn ìjòyè sì pín ara wọn ṣẹ́yìn in gbogbo ènìyàn Júdà.

Nehemáyà 4

Nehemáyà 4:14-23