Nehemáyà 4:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lákòókò yìí, àwọn ènìyàn Júdà wí pé, “Agbára àwọn òṣìṣẹ́ ti dínkù, àlàpà púpọ̀ ni ó wà tó bẹ́ẹ̀ tí àwa kò fi le è mọ odi náà.”

Nehemáyà 4

Nehemáyà 4:8-13