Nehemáyà 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òru, mo jáde lọ sí àfonífojì ibodè sí ìhà kànga Jákálì àti sí ẹnu ibodè jààtàn àti ẹnu ibodè rẹ̀ èyí tí ó ti wó lulẹ̀, tí a ti fi iná sun.

Nehemáyà 2

Nehemáyà 2:7-18