Nehemáyà 13:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣáájú èyí a ti fi Élíáṣíbù àlùfáà ṣe alákoṣo yàrá ìkó nǹkan ilé Ọlọ́run wa sí. Ó súnmọ́ Tóbíyà pẹ́kípẹ́ki.

Nehemáyà 13

Nehemáyà 13:1-9