Nehemáyà 13:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìdajì àwọn ọmọ wọn ń sọ èdè Áṣídódù tàbí èdè ọ̀kan lára àwọn ènìyàn mìíràn tó kù, wọn kò sì mọ bí a ṣe ń ṣọ èdè Júdà.

Nehemáyà 13

Nehemáyà 13:22-29