Nehemáyà 12:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣálù, Ámókì, Hílíkíyà, àti Jédáyà.Wọ̀nyí ni olóórí àwọn àlùfáà àti àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ wọn ní ìgbà ayé e Jéṣúà.

Nehemáyà 12

Nehemáyà 12:5-9