Nehemáyà 12:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti Bétì Gílígálì, àti láti àwọn agbègbè Gébà àti Ásímáfétì, nítorí àwọn akọrin ti kọ́ àwọn ìletò fún ra wọn ní agbégbé Jérúsálẹ́mù.

Nehemáyà 12

Nehemáyà 12:20-30