Nehemáyà 12:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mátanáyà, Bákíbúkáyà, Ọbadáyà, Mésúlámù, Tálímónì àti Ákúbù ni aṣọ́nà tí wọ́n ń ṣọ yàrá ìpamọ́ ní ẹnu ibodè.

Nehemáyà 12

Nehemáyà 12:21-27