Nehemáyà 12:17-20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

17. ti ìdílé Ábíjà, Ṣíkírì;ti ìdílé Míníámínì àti ti ìdílé Móádíà, Pílítaì;

18. ti ìdílé Bílígà, Ṣámúyà;ti ìdílé Ṣémáyà, Jéhónátanì;

19. ti ìdílé Jóíáríbù, Máténáyì;ti ìdílé Jédáíáyà, Húsì;

20. ti ìdílé Ṣálù, Káláyì;ti ìdílé Ámókì, Ébérì;

Nehemáyà 12