Nehemáyà 11:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóẹ́lì ọmọ Ṣíkírì ni olóórí òṣìṣẹ́ ẹ wọn, Júdà ọmọ Haṣenuáyà sì ni olórí agbégbé kejì ní ìlú náà.

Nehemáyà 11

Nehemáyà 11:4-16