Nehemáyà 11:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àti Maaṣeayà ọmọ Bárúkì, ọmọ Koli-Hóṣè, ọmọ Haṣaíyà, ọmọ Ádáyà, ọmọ Joiaribù, ọmọ Ṣekaráyà, ìran Ṣélà.

Nehemáyà 11

Nehemáyà 11:1-6