Nehemáyà 11:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Petaiayọ̀ ọmọ Meṣeṣabélì, ọ̀kan nínú àwọn Ṣérà ọmọ Júdà ní aṣojú ọba nínú ohun gbogbo tí ó jẹ mọ́ ti àwọn ènìyàn náà.

Nehemáyà 11

Nehemáyà 11:14-27