Nehemáyà 11:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àti àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ rẹ̀ tí wọ́n jẹ́ alágbára ọkúnrin jẹ́ méjìdínláàdọ́je (128). Olórí òṣìṣẹ́ ẹ wọn ni Sábídíelì ọmọ Hágédólímù.

Nehemáyà 11

Nehemáyà 11:8-24