Nehemáyà 10:1-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Àwọn tí ó fi èdìdì dìí ni:Nehemáyà baálẹ̀, ọmọ Hakaláyà.Ṣedekáyà

2. Ṣeráyà, Aṣaráyà, Jeremáyà,

3. Páṣùn, Ámáráyà, malikíjà,

4. Hátúsì, Ṣebanáyà, málúkì,

5. Hárímù, Meremótì, Obadáyà,

6. Dáníẹ́lì, Gínétónì, Bárúkì,

7. Mésúlámù, Ábíjà, Míjámínì,

8. Mááṣáyà, Bílígáì àti Ṣémáyà.Àwọn wọ̀nyí ni àwọn àlùfáà.

9. Àwọn ọmọ Léfì:Jéṣúà ọmọ Aṣanáyà, Bínúyì ọ̀kan nínú àwọn ọmọ Hénédédì, Kádímélì,

Nehemáyà 10