Náhúmù 3:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò da ẹ̀gbin tí ó ni ìríra sí ọ ní ara,èmi yóò sì sọ ọ́ di aláìmọ́èmi yóò sì sọ ọ́ di ẹlẹ́yà.

Náhúmù 3

Náhúmù 3:1-9