Náhúmù 3:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ègbé ni fún ìlú ẹ̀jẹ̀ nì,gbogbo rẹ̀ kún fún èké,àti olè,ìja kò kúrò!

2. Ariwo pàṣán àti ariwokíkùn kẹ̀kẹ́ ogunàti jíjó ẹṣin àti gbígbọ̀nkẹ̀kẹ́ ogun jìgìjìgì!

Náhúmù 3