Náhúmù 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn apanirun ti dìde sí ọ, ìwọ Nínéfèpa ilé-ìsọ́ mọ́,ṣọ́ ọ̀nà náàdi àmùrè, ẹ̀gbẹ́ rẹ kí ó le,múra gírí.

Náhúmù 2

Náhúmù 2:1-7