Náhúmù 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa lọ́ra láti bínú, ó sì tóbi ní agbára; Olúwa kì yóò fi àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ sílẹ̀ láì jìyà.Ọ̀nà rẹ̀ wà nínú ààjà àti nínú ìjì,Ìkùùku sánmọ̀ sì ni eruku ẹsẹ̀ rẹ̀.

Náhúmù 1

Náhúmù 1:1-9